English (en)
Animation
Animation is the process of creating
moving images by displaying a
sequence of individual frames, often
drawings or computer-generated
graphics, to give the illusion of
motion and bring characters or
scenes to life.
Yorùbá (yo)
- Ìsọdààyè
Decomposition: Sísọ nǹkan di ààyè. The process of bringing inanimate thing to life.
[Total: 0 Average: 0]
- Ìsàwòrándààyè
Decomposition: Ìlànà tí à ń gbà sọ àwòrán/ẹ̀dá oníṣe (tí a yà) di ààyè - the process of converting still images to moving images.
[Total: 0 Average: 0]
- Ìgbẹ́mìíwàwòrán
Decomposition: Derived from the prefix ì- which denotes the process, combined with gbẹ́mìíwàwòrán.
[Total: 0 Average: 0]