English (en)
Biometric
Biometric refers to the measurement
and analysis of unique physical or
behavioural traits, like
fingerprints or facial recognition,
for identification.
Yorùbá (yo)
- Ìdánimọ̀-àbùdá-ara
Decomposition: Àwọn àbùdá àdáni ara ẹni tí ó yàtọ̀ sí ti ẹlòmíràn, tí a fi ń dá ẹni mọ̀ – unique traits used as personal identifiers.
• Ìdánimọ̀-àbùdá-ara òtẹ̀ ìka – fingerprint biometric
• Ìdánimọ̀-àbùdá-ara ojú – facial biometric
• Ìdánimọ̀-àbùdá-ara ẹyinjú – iris (scan) biometric
• Ìdánimọ̀-àbùdá-ara ohùn – voice biometric
[Total: 0 Average: 0]