English (en)
Adiabatic Process
A process where no heat is
transferred to or from the
system.
Yorùbá (yo)
- Ìlànà àìfàyègbooru
Decomposition: Ìyípadà tó wáyé nínúu gáàsì láì jẹ́ pé ooru kankan wọlé tàbí jáde. Adiabatic means not letting heat pass through, either in or out.
[Total: 0 Average: 0]
- Ìlànà Ìdínàmóoru
Decomposition: Ìlànà ìsénà mọ́ ooru gbígbóná láti má jáde láti inú sí ìta àti láti má wọlé láti ìta. A process in which no heat is added to or removed from a system. That means the system doesn't gain or lose heat from its surroundings.
[Total: 0 Average: 0]