English (en)
Bearing
In engineering, a bearing is a
machine element that constrains
relative motion and reduces
friction between moving parts,
typically to facilitate smooth
rotation or linear movement.
Bearings are crucial in
supporting loads (radial, axial,
or combined) while allowing
controlled motion with minimal
energy loss.
Yorùbá (yo)
- Adínjẹkù
Decomposition: A-dín-ìjẹ-irin-kù (Ohun tí ó ń dín irin jíjẹ kù), bí i àpẹẹrẹ, ìmúdiyíyọ̀. That which reduces friction, for instance, lubricant.
[Total: 0 Average: 0]
- Amẹ́rọyọ̀kùlùlù
Decomposition: Ohun tí ó ń jẹ́ kí ohun èlo méjì tó farakanra nínú ẹ̀rọ máa lọ síwá-sẹ́yìn nírọ̀rùn láì para wọn lára. Àwọn ohun èlò yìí le jẹ́ irin, ike, àwo (ceramics), rọ́bà, abbl. A part that helps things move smoothly and reduce friction between moving parts. It's usually used where two parts rub or rotate against each other—like in a car wheel or a fan.
[Total: 0 Average: 0]