Combustion chamber

English (en)

Combustion chamber
An enclosed space in which combustion 
takes place, especially in an engine.

Other languages: Hausa, Igbo

Related terms
Carburator

 

 

Yorùbá (yo)

  • Kóló ìsọdiná

Decomposition: Kóló níbi tí a ti ń sọ nǹkan di iná.

[Total: 0 Average: 0]

  • Kóló ìjépo

Decomposition: Ìyẹ̀wù (bí i kóló tí à ń fi owó pamọ́ sí) fún ìjópọ̀ epo-rọ̀bì àti afẹ́fẹ́. A chamber of a combustion engine in which the fuel or air mix is burned.

[Total: 0 Average: 0]

  • Ilé-agbára alápòótí-ina

Decomposition: Abala tàbí agbọn kan tó dàbí àpótí nínú ẹ̀rọ níbi tí epo ti máa ń jó kí ẹ̀rọ le ṣiṣẹ́. The part of an engine where fuel burns to produce energy. The combustion chamber is like a small room where controlled explosions happen to power the engine.

[Total: 0 Average: 0]

 

    Log Your Own Term

    Do you think there could be a better term for the above? Please log your suggestion here.

    Scroll to top