English (en)
Compression Ratio
Force that acts outward on a body
moving in a circular path.
Yorùbá (yo)
- Ìfìsẹ́gbẹ̀ẹ́ ń'nú òbìrìkítí
Decomposition: Fífì sí ẹ̀gbẹ́ ohun tí ó wà nínú òbìrìkítí. Tilting to the side when something is rotating.
[Total: 0 Average: 0]
- Agbára ìfìsẹ́gbẹ̀ẹ́ olóbìrípo
Decomposition: Agbára àìrí tó ń fi ohun tó wà nínú òbìrípo sí ẹ̀gbẹ́. The apparent force that seems to push an object outward when it's moving in a circle.
[Total: 0 Average: 0]