English (en)
Efficiency
Ratio of useful work output to total
energy input.
Yorùbá (yo)
- Ìjẹ́ṣẹ́pé
Decomposition: Jíjẹ́ iṣẹ́ tí ó yẹ kí nǹkan tàbí ẹ̀rọ ó ṣe pé dé ojú àmì (mùṣèmúṣèe rẹ̀ já múṣémúṣé)- the state of having full capability or being productive.
[Total: 0 Average: 0]