English (en)
Gasket
A seal used to prevent leakage between
two mating surfaces.
Yorùbá (yo)
- Ohun-èlò Adíǹkanpa
Decomposition: Ohun tí a fi dí àwọn nǹkan bí i atẹ́gùn, omi, epo tàbí gáàsì mọ́ inú ohun èlò kan tàbí ẹ̀yà ẹ̀ró láti má jáde.
[Total: 0 Average: 0]
- Àdípa
Decomposition: Ohun tí ó ń di àlàfo tí ó wà láàárín nǹkan méjì kí ó ba máà á jò. Sealing device for filling the space between two flat surface to prevent leakage.
[Total: 0 Average: 0]