English (en)
Isothermal Process
A process occurring at a constant
temperature.
Yorùbá (yo)
- Àìyípada ìwọ̀n ìgbónágbóoru
Decomposition: Wíwà ìwọ̀n ìgbónágbóoru bákan náà fún ìgbà pípẹ́ láì yí padà. Temperature (thermal) remaining the same or constant (iso) throughout.
[Total: 0 Average: 0]