Aerodynamics

English (en)

Aerodynamics
Study of air motion and its 
interaction with solid objects.

Other languages: Hausa, Igbo

Related terms
Hydraulics

 

Yorùbá (yo)

  • Ìmọ̀ ẹ̀rọ ìrìn inú afẹ́fẹ́

Decomposition: Ìmọ̀ ẹ̀rọ tó ní ṣe pẹ̀lú u bí àwọn ohun èlò ṣe lè lo afẹ́fẹ́ fún ìrìn yálà lórí ilẹ̀ tàbí lórí òfurufú.

[Total Votes: 0]

  • Ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ egbé

Decomposition: Ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa egbé tí ó ní í ṣe pẹ̀lú ìbáṣepọ̀ láàárín àwọn ohun tí ó ń fò nínú afẹ́fẹ́ àti afẹ́fẹ́. The science of things that fly or move through air.

[Total Votes: 0]

 

    Please break down the word into its constituent parts to understand its meaning. Which base/root words, affixes, and/or prefixes are combined to form this term?

    Scroll to top