English (en)
Anastomosis
The surgical connection of two
structures, e.g. connections between
blood vessels or between other tubular
structures such as intestine.
Other languages: Hausa, Igbo
Related terms
Surgery
Yorùbá (yo)
- Ìfabẹṣàsopọ̀
Decomposition: Fífi iṣẹ́ abẹ ṣe àsopọ̀ àwọn ètò inú ara méjì.
[Total Votes: 0]
- Àmúsopapọ̀ètòara
Decomposition: Mímú àwọn ètò ara méjì so mọ́ ara wọn láti ṣiṣẹ́ papọ̀. Connection or joining diverge structure together to intercommunicate.
[Total Votes: 0]
