English (en)
Accelerator
An accelerator is a tool, program,
or mechanism that increases speed
or efficiency.
Yorùbá (yo)
- Amúyàárabóhun
Decomposition: Amú-ìyárabóhun - What helps in speeding up.
[Total: 0 Average: 0]
- Aṣàgbàsọ-ìyára
Decomposition: Ohun tí ó ń ṣe ìgbàjọ ìyára kí ó tó sọ ọ́ sílẹ̀. That which forcefully releases accumulated speed.
[Total: 0 Average: 0]
- Amóhunyára
Decomposition: A mú nǹkan yára.
[Total: 0 Average: 0]