English (en)
Ammeter
Instrument for measuring electric
current.
Yorùbá (yo)
- Ẹ̀rọ ìwọ̀n mànàmáná
Decomposition: Ohun-èlò tí a fi ń ṣe òǹdiwọ̀n ipa tàbí agbára iná mànàmáná. An instrument used in measuring the current of electricity in a circuit.
[Total: 0 Average: 0]
- Ẹ̀rọ ìfidíwọ̀n mànàmáná
Decomposition: Ohun èlò tí a fi ń ṣe òdiwọ̀n iná mànàmáná.
[Total: 0 Average: 0]
- Ohun èlò ìwọn agbára iná
Decomposition: Instrument used to measure electric current.
[Total: 0 Average: 0]