English (en)
Antivirus
Antivirus is software designed
to detect, prevent, and remove
malicious software (malware),
such as viruses, worms, and
trojans. It scans and monitors
systems to protect against cyber
threats and maintain security.
Yorùbá (yo)
- Iṣẹ́ àìrídìmú atako aṣèpalárafẹ́rọ
Decomposition: Since it is a software designed to work against malware.
[Total: 0 Average: 0]
- Aṣàtakò-àrùn
Decomposition: A ṣe àtakò àrùn - A software that attacks viruses, worms, etc.
[Total: 0 Average: 0]
- Aṣàtako-amúpalárabẹ́rọ
Decomposition: Iṣẹ́ àìrídìmú tí ó ń ṣe àtakò tí ó sì tún ń gbógunti àwọn irúfẹ́ iṣẹ́ àìrídìmú tí ó ń mú ìpalára bá ẹ̀rọ-ayárabíàṣá - software that fights against malicious programmes by detecting, preventing, and removing them.
[Total: 0 Average: 0]