English (en)
Bending Moment
The internal moment that induces
bending of a beam.
Yorùbá (yo)
- Amúrintẹ̀
Decomposition: Ohun tó ń mú kí irin tẹ̀. The force that causes a beam or shaft to bend.
[Total: 0 Average: 0]
- Agbára amóhunèlòtẹ̀
Decomposition: Amú-ohun-èlò-tẹ̀. Agbára tó ń mú kí òpó gbọọrọ agbẹrù-sórí (beam) tàbí ohun èlò mìíràn tẹ̀. Àwọn ohun èlò yìí le jẹ́ irin, kannkéré, igi, abbl. Bending moment is the force that makes a beam or any other object bend.
[Total: 0 Average: 0]