English (en)
BRCA
Breast Cancer genes (BRCA1 and
BRCA2) associated with higher risk
of several cancers.
Other languages: Hausa, Igbo
Related terms
Cancer
Yorùbá (yo)
- Ìràn jẹjẹrẹ ọmú
Decomposition: Breast cancer genes - àwọn ìran (genes) jẹjẹrẹ (cancer) ọmú (breast) tí wọ́n ní (that have) ewu onírúurú (various risk) jẹjẹrẹ (cancer) tí ó pọ̀ (that is much).
[Total Votes: 0]
- Àjẹbí Jẹjẹrẹ Ọmú
Decomposition: Àwọn àjẹbí (àjogúnbá inú ẹ̀jẹ̀) tí ó ní ṣe pẹ̀lú ewu jẹjẹrẹ ọmú tí ó pọ̀ jọjọ.
[Total Votes: 0]
