Mechanical Advantage

English (en) Mechanical Advantage Ratio of output force to input force in a machine. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Engine     Yorùbá (yo) Ipa ẹ̀rọ Decomposition: Iye ipa tí ẹ̀rọ́ kó láti mú iṣẹ́ rọrùn. How much impact a machine has in making tasks easier.  

Lathe

English (en) Lathe Machine tool used for shaping materials by rotating them against a cutting tool. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Jig     Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ agbẹ́gigbẹ́rin Decomposition: Ẹ̀rọ tí a fi ń gbẹ́gi àti irin. A machine tool used for shaping materials like wood or metal.  

Linear Actuator

English (en) Linear Actuator Device that creates motion in a straight line. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Lubrication     Yorùbá (yo) Ètò ìsúnsíwásẹ́yìn Decomposition: Ohunkóhun tàbí nǹkan tí ó máa ń sún síwájú sún ṣẹ́yìn láì yà bàrà kúrò lójú ilà kan náà. A system that moves or pushes or pulls things back...

Load

English (en) Load The force or weight supported by a structure or component. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Lever     Yorùbá (yo) Ẹrù Decomposition: This is the force or weight that is applied to a structure or object.  

Lever

English (en) Lever A simple machine used to amplify force. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Load     Yorùbá (yo) Agbẹ́rùwúwosókè Decomposition: Ohun-èlò tí ó ń gbé nǹkan tí ó wúwo sókè. A tool used to move or lift heavy objects with less effort.  

Lubrication

English (en) Lubricator Application of a substance to reduce friction between surfaces. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Linear Actuator     Yorùbá (yo) Ìmúdiyíyọ̀ Decomposition: Fífi ohun a mú nǹkan yọ̀ gẹ̀ẹ̀rẹ̀ pa nǹkan kí ó bá yọ. Application of lubricant.  

Key

English (en) Key A component that transmits torque between shafts and gears. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Nozzle     Yorùbá (yo) Aṣàsúnsí Decomposition:  Ohun tí ó ń ṣe àsúnsí àti àsopọ̀ mọ́ ọ̀pá ayíbírí. An element that connects a rotating machine element to a shaft.  

Kinetic Theory

English (en) Kinetic Theory Theory that explains the behaviour of gases based on their molecular motion. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Kinematic, Kinetic Energy, Kinematic Pair     Yorùbá (yo) Èrò Ìhùwàsí Ìṣípòpadà Decomposition: Èrò orí tí ó ń ṣe àlàyé ìhùwàsí àwọn nǹkan nípasẹ̀ ìṣípòpadà àti agbára nǹkan gíngín. Explanation of the behaviour...

Kinematic Pair

English (en) Kinematic Pair Two links or components that are connected in a mechanical system. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Kinematic, Kinetic Energy     Yorùbá (yo) Oríkèé-ìṣepọ̀ Ìṣínípòpadà Decomposition: Oríkèéríkèé ìbáṣepọ̀ láàárin ẹ̀yà ara ẹ̀rọ méjì tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ pọ̀ kí ìṣínípòpadà ó tó wáyé. A joint between two parts of a machine...

Rotor

English (en) Rotor A rotating part of a machine, such as a motor or turbine. Other languages: Hausa, Yoruba Related terms Igbo (ig) Akụkụ Igwe Kentụgharị Decomposition: Akụkụ Igwe Kentụgharị - the part of a machine that rotates.  

Scroll to top