Impeller

English (en) Impeller A rotating component used to move fluids in pumps and turbines. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Fan     Yorùbá (yo) Afátẹ́gún-inú-ẹ̀rọ Decomposition: Ẹ̀rọ afátẹ́gún tó wà nínú ẹ̀rọ ìfami, ọkọ̀ ojú omi àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. A rotating part (a fan) inside pumps, boats, etc.  

Instrumentation

English (en) Instrumentation Tools and devices used to measure and control physical quantities. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Flywheel     Yorùbá (yo) Ohun-èlò ìdiwọ̀n Decomposition: Àwọn ohun-èlò tí à ń lò fi ṣe òdiwọn, òǹkà-iye tàbí àkóso iye nǹkan. Tools & devices used to measure or control variables.  

Isothermal Process

English (en) Isothermal Process A process occurring at a constant temperature. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Temperature     Yorùbá (yo) Àìyípada ìwọ̀n ìgbónágbóoru Decomposition: Wíwà ìwọ̀n ìgbónágbóoru bákan náà fún ìgbà pípẹ́ láì yí padà. Temperature (thermal) remaining the same or constant (iso) throughout.  

Internal Combustion Engine

English (en) Internal Combustion Engine Engine where combustion occurs inside the engine. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Combustion chamber     Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ ìjépo tinú-ẹ̀rọ Decomposition: Ẹ̀rọ tí ó ń pèsè agbára nípasẹ̀ jíjó epo rọ̀bì àti afẹ́fẹ́ papọ̀ nínú ẹ̀rọ tìkalárarẹ̀. A type of engine that generates power by burning fuel inside the...

Inertia

English (en) Inertia Resistance of an object to changes in its state of motion. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Dynamics     Yorùbá (yo) Ìtako-ìṣínípò Decomposition: Titako ìṣínípòpadà nǹkan tàbí ìtako ìyípadà nǹkan bí ó ṣe wà. Tendency of an object to resist a change in its motion or its static position.  

Hypoid Gear

English (en) Hypoid Gear A type of gear where the axes do not intersect. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Gear     Yorùbá (yo) Ayíbírí eléyín kọrọdọ Decomposition: Awo ayíbírí tí àwọn eyín-in rẹ̀ tẹ̀ kọrọdọ. Wheels with curved or spiral-shaped teeth.  

Heat Transfer

English (en) Heat Transfer Movement of thermal energy from one body or material to another. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Heat Exchanger     Yorùbá (yo) Ìtari Ooru Decomposition:   

Hysteresis

English (en) Hysteresis Lag between input and output in a material or system. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Deformation     Yorùbá (yo) Ìlọ́rapadàbọ̀sípò Decomposition: Lílọ ara láti padà bọ̀ sí ipò. Lagging behind or delay in getting back to original shape after a cause.  

Hydraulics

English (en) Hydraulics Study of fluid mechanics involving liquid pressure and flow. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Coolant     Yorùbá (yo) Afomiṣagbára Decomposition: Ohunkóhun tí ó ń lo agbára omi fi ṣiṣẹ́. An object, tool, device or machine that uses liquid to transmit power or force. Example: ìjánu afomiṣagbára - hydraulic brake.  

Heat Exchanger

English (en) Heat Exchanger Device for transferring heat between two or more fluids. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Coolant     Yorùbá (yo) Aṣàtaré ooru Decomposition: Ohun tí ó ń ṣe àtaré ooru láti ibìkan sí ibòmíràn. A device that transfers heat from one place to another.  

Scroll to top