Jack

English (en) Jack A device used to lift heavy loads. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Load     Yorùbá (yo) Ajẹ́rùsókè Decomposition: Ohun-èlò tí a fi ń já ẹrù tàbí nǹkan tó wúwo sókè. A tool used to lift heavy load or things.  

Joint

English (en) Joint A connection between two mechanical components. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Friction     Yorùbá (yo) Àsopọ̀ Decomposition: Connection between two components. Oríkèé Decomposition: Oríkèéríkèé (ojú ibi tí ohun méjì ti fẹnubọra). A point where two components connect.  

Jet Engine

English (en) Jet Engine Engine that propels an aircraft by expelling jet streams of gases. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Engine     Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ agbọ́kọ̀-òfuuufú-fò Decomposition: Ẹ̀rọ alepo rọ̀bì tàbí afẹ́fẹ́ àmúṣagbára tí ó ń mú kí ọkọ̀ inú òfuurufú ó fò lókè. An engine that powers aircraft by turning fuel into...

Jig

English (en) Jig A tool used to guide the movement of tools or workpieces. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Gauge     Yorùbá (yo) Atọ́nà ohun èlò Decomposition: Tool that guides the movement of tools  

Impeller

English (en) Impeller A rotating component used to move fluids in pumps and turbines. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Fan     Yorùbá (yo) Afátẹ́gún-inú-ẹ̀rọ Decomposition: Ẹ̀rọ afátẹ́gún tó wà nínú ẹ̀rọ ìfami, ọkọ̀ ojú omi àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. A rotating part (a fan) inside pumps, boats, etc.  

Instrumentation

English (en) Instrumentation Tools and devices used to measure and control physical quantities. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Flywheel     Yorùbá (yo) Ohun-èlò ìdiwọ̀n Decomposition: Àwọn ohun-èlò tí à ń lò fi ṣe òdiwọn, òǹkà-iye tàbí àkóso iye nǹkan. Tools & devices used to measure or control variables.  

Isothermal Process

English (en) Isothermal Process A process occurring at a constant temperature. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Temperature     Yorùbá (yo) Àìyípada ìwọ̀n ìgbónágbóoru Decomposition: Wíwà ìwọ̀n ìgbónágbóoru bákan náà fún ìgbà pípẹ́ láì yí padà. Temperature (thermal) remaining the same or constant (iso) throughout.  

Internal Combustion Engine

English (en) Internal Combustion Engine Engine where combustion occurs inside the engine. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Combustion chamber     Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ ìjépo tinú-ẹ̀rọ Decomposition: Ẹ̀rọ tí ó ń pèsè agbára nípasẹ̀ jíjó epo rọ̀bì àti afẹ́fẹ́ papọ̀ nínú ẹ̀rọ tìkalárarẹ̀. A type of engine that generates power by burning fuel inside the...

Inertia

English (en) Inertia Resistance of an object to changes in its state of motion. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Dynamics     Yorùbá (yo) Ìtako-ìṣínípò Decomposition: Titako ìṣínípòpadà nǹkan tàbí ìtako ìyípadà nǹkan bí ó ṣe wà. Tendency of an object to resist a change in its motion or its static position.  

Hypoid Gear

English (en) Hypoid Gear A type of gear where the axes do not intersect. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Gear     Yorùbá (yo) Ayíbírí eléyín kọrọdọ Decomposition: Awo ayíbírí tí àwọn eyín-in rẹ̀ tẹ̀ kọrọdọ. Wheels with curved or spiral-shaped teeth.  

Scroll to top