English (en) Heat Transfer Movement of thermal energy from one body or material to another. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Heat Exchanger Yorùbá (yo) Ìtari Ooru Decomposition:
Category: Engineering
Hysteresis
English (en) Hysteresis Lag between input and output in a material or system. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Deformation Yorùbá (yo) Ìlọ́rapadàbọ̀sípò Decomposition: Lílọ ara láti padà bọ̀ sí ipò. Lagging behind or delay in getting back to original shape after a cause.
Hydraulics
English (en) Hydraulics Study of fluid mechanics involving liquid pressure and flow. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Coolant Yorùbá (yo) Afomiṣagbára Decomposition: Ohunkóhun tí ó ń lo agbára omi fi ṣiṣẹ́. An object, tool, device or machine that uses liquid to transmit power or force. Example: ìjánu afomiṣagbára - hydraulic brake.
Heat Exchanger
English (en) Heat Exchanger Device for transferring heat between two or more fluids. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Coolant Yorùbá (yo) Aṣàtaré ooru Decomposition: Ohun tí ó ń ṣe àtaré ooru láti ibìkan sí ibòmíràn. A device that transfers heat from one place to another.
Gearbox
English (en) Gearbox A mechanical device that changes the speed and torque of a machine. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Gear Yorùbá (yo) Àpótí Òṣàkóso-ìyára Decomposition: Àpótí tí àwọn òṣàkóso ìyára ìrìn wà. The enclosed casing that holds gears and other components that manage the level of motion or torque.
Gauge
English (en) Gauge Instrument used to measure physical quantities. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Bearing Yorùbá (yo) Adíwọ̀n Decomposition: Ohun èlò tí a fi ń ṣe ìdíwọ̀n nǹkan Asòdiwọ̀n nǹkan Decomposition: Ohun èlò tí ó ń 'sọ' ìwọ̀n nǹkan.
Gasket
English (en) Gasket A seal used to prevent leakage between two mating surfaces. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Joint Yorùbá (yo) Ohun-èlò Adíǹkanpa Decomposition: Ohun tí a fi dí àwọn nǹkan bí i atẹ́gùn, omi, epo tàbí gáàsì mọ́ inú ohun èlò kan tàbí ẹ̀yà ẹ̀ró láti má jáde. Àdípa Decomposition: Ohun tí ó...
Gear
English (en) Gear A rotating machine part with cut teeth that meshes with another gear to transmit torque. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Brake Yorùbá (yo) Òṣàkóso-ìyára Decomposition: Ohun tí ó ń ṣe àkóso ìyára ìrìn. A component that manages the level of motion or torque.
Flywheel
English (en) Flywheel A rotating wheel used to store rotational energy. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Engine Yorùbá (yo) Àwo-ayíbírí-ẹsẹ̀-ọkọ̀ Decomposition: Àwo ayíbírí tí ó wà ní ẹsẹ̀ ọkọ̀ tí ó ń mú kí ọkọ̀ ó fà síwásẹ́yìn. The spinning disc (wheels) that propels a vehicle.
Fluid Dynamics
English (en) Fluid Dynamics Study of fluids in motion and their interactions. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Dynamics Yorùbá (yo) Ìlọbọ̀ omi Decomposition: Lílọ àti bíbọ̀ omi nínú ẹ̀rọ. The movement or flow of fluid in a system.