Fan

English (en) Fan A device used to move air or gases. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Coolant     Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ afátẹ́gùn Decomposition: Ẹ̀rọ a-fẹ́-atẹ́gùn.  

Fuel Injector

English (en) Fuel Injector Device that introduces fuel into the combustion chamber. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Combustion chamber     Yorùbá (yo) Afeposẹ́rọ Decomposition: Ohun tó ń fa epo sínú kóló ìsodina inú ẹ̀rọ - the object that carries fuel into the combustion chamber in the engine. Afeposẹ́rọ Decomposition: Ohun tó ń ta epo...

Friction

English (en) Friction Resistance to motion between two surfaces in contact. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Deformation     Yorùbá (yo) Ìgbora Decomposition: Kí ohun méjì ó ra ara wọn pọ̀ tàbí gbo ara papọ̀. Resistance to the motion between two objects sliding or in contact.  

Entropy

English (en) Entropy Measure of disorder or randomness in a system. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Inertia     Yorùbá (yo) Òdiwọ̀n àìlétò Decomposition: Òdiwọ̀n àìní ètò (disorder) tàbí ọ̀kan-ò-jọ̀kan (randomness) nínú ẹ̀rọ, iṣẹ́ tàbí 'ìwà' nǹkan (the state of being) of something. Ìwọ̀n Ìdàrúdàpọ̀ Decomposition: Òdiwọ̀n ìdàrú àti ìdàpọ̀ nínú ètò kan tàbí òmíràn....

Elasticity

English (en) Elasticity Ability of a material to return to its original shape after deformation. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Deformation, Efficiency     Yorùbá (yo) Agbára ìpadàbọ̀sípò Decomposition: Agbára láti padà sí ipò. Agbára ìbọ̀ọ́pò Decomposition:   

Exhaust System

English (en) Exhaust System Components that channel exhaust gases away from the engine. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Heat Exchanger     Yorùbá (yo) Ètò ìgbèéfín jáde Decomposition: Ètò tí ó ń gbá èéfín tí ó ń ti ara epo rọ̀bì inú ẹ̀rọ jọ tí ó sì ń gbá a jáde síta - the...

Engine

English (en) Engine A machine that converts fuel into mechanical energy. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Instrumentation     Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ Decomposition:  

Efficiency

English (en) Efficiency Ratio of useful work output to total energy input. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Dynamic Balance     Yorùbá (yo) Ìjẹ́ṣẹ́pé Decomposition: Jíjẹ́ iṣẹ́ tí ó yẹ kí nǹkan tàbí ẹ̀rọ ó ṣe pé dé ojú àmì (mùṣèmúṣèe rẹ̀ já múṣémúṣé)- the state of having full capability or being productive.  

Dynamic Balance

English (en) Dynamic Balance Condition where the center of mass is aligned with the axis of rotation. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Bearing     Yorùbá (yo) Okun Ìgbáradúró Decomposition: Okun tàbí agbára láti gbé ara dúró láìfì síwá-sẹ́yìn tàbí fì sí ọ̀tún àti òsì, nígbàtí à ń rìn tàbí nígbàtí a wà lójú kan....

Drilling Machine

English (en) Drilling Machine Equipment used for drilling holes in materials. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Accelerator, Brake     Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ ìluhò Decomposition: Ẹ̀rọ tí a fi ń lu ihò tàbí dá ihò lu sí nǹkan.  

Scroll to top