English (en) Placenta An organ that supplies oxygen and nutrients to a developing baby. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Oxygenation Yorùbá (yo) Olubi ọmọ Decomposition:
Category: Medical
Pelvis
English (en) Pelvis The lower part of the trunk that supports abdominal organs. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Renal pelvis Yorùbá (yo) Eégún ìkòkò-ìdí Decomposition: Eégún tí ó wà ní ìdí, tí a fi ń jókòó.
Oxygen saturation
English (en) Oxygen saturation The amount of oxygen carried in the blood. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Anoxia Yorùbá (yo) Ìtọ̀ká òyì-iná nínú ẹ̀jẹ̀ Decomposition: Ìtọ̀ká òyì-iná inú ẹ̀jẹ̀ tí àwọn pádi-ẹ̀jẹ̀ pupa ń gbé láti ẹ̀dọ̀-fóró káàkiri ara. Ìwọ̀n afẹ́fẹ́ abẹ́mìírẹ́ tó wà nínú ẹ̀jẹ̀ Decomposition:
Ovary
English (en) Ovary One of the female reproductive organs that produce eggs and hormones. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Progesterone Yorùbá (yo) Ibú-ẹyin Decomposition: Ibi tí ìṣẹ̀dá ẹyin ti ń wáyé.
Neurology
English (en) Neurology The branch of medicine dealing with the nervous system. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Neuroimaging Yorùbá (yo) Ìmọ̀ ètò ẹ̀sọ Decomposition: Ìmọ̀ nípa ètò àwọn ẹ̀sọ ara.
Nausea
English (en) Nausea A feeling of sickness or urge to vomit. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Emesis Yorùbá (yo) Èébì Decomposition: Èbíbì.
Miscarriage
English (en) Miscarriage Loss of a pregnancy before the baby can survive outside the womb. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Abortion Yorùbá (yo) Ìṣẹ́nú Decomposition: Ìpàdánù oyún inú/ìṣẹ́yún inú.
Metabolism
English (en) Metabolism The chemical processes that maintain life in the body. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Metabolic disease, Metabolic regulation Yorùbá (yo) Àpapọ̀-ẹlà aṣàyídà Decomposition: Àwọn ẹlà ara tí ó ń ṣe àkóso àyídáyidà ohun ìwàláàyè bíi èémí, oúnjẹ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ fún ìlò ara. The chemical processes that change substances in...
Menstruation
English (en) Menstruation The monthly shedding of the womb lining. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Menopause Yorùbá (yo) Nǹkan oṣù Decomposition: Ẹ̀jẹ̀ tí ó máa ń jáde láti ojú ara obìnrin lóṣooṣù.
Menopause
English (en) Menopause The time when menstruation permanently stops. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Menstruation Yorùbá (yo) Ìdáwọ̀-dúró nǹkan oṣù Decomposition: Àsìkò tí nǹkan oṣù dáwọ́ dúró pátápátá.
