English (en) Epidural A type of pain relief injected into the spine, often used during labour. Other languages: Hausa, Igbo Related terms TENS Yorùbá (yo) Abẹ́rẹ́ àyíká ọ̀pá ẹ̀yìn Decomposition: Ìlànà gígún 'ni ní abẹ́rẹ́ ní àwọn àyíká ọ̀pá ẹ̀yìn láti mú ìbàdí dé ẹsẹ̀ kú tàètae. Abẹ́rẹ́ ọ̀pá ẹ̀yìn apàrora amúbàdídẹ́sẹ̀kú Decomposition: Abẹ́rẹ́ tí...
Category: Medical
Endocrine system
English (en) Endocrine system The system of glands that produce hormones. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Hormone Yorùbá (yo) Ètò ẹṣẹ́ ojera Decomposition: Ètò àwọn ẹṣẹ́ tí ó máa sun/ṣẹ́ oje nínú ara. System of glands that secrete hormones in the body.
Endometriosis
English (en) Endometriosis A condition where tissue similar to the womb lining grows outside the uterus. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Womb (uterus) Yorùbá (yo) Àrùn wíwú iṣan ilé ọlẹ̀ Decomposition: Àrùn tí ó máa mú kí àwọn iṣan tí ó yí ilé ọlẹ̀ ká ó wú. Ìṣù ìta afarajọ ilé-ọmọ Decomposition: Irú àìlera...
Embryo
English (en) Embryo A developing baby in the womb during the early stages of pregnancy. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Fetus Yorùbá (yo) Ọlẹ̀ Decomposition: Oyún inú tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń di ọmọ.
Edema
English (en) Edema Swelling caused by excess fluid trapped in body tissues. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Inflammation Yorùbá (yo) Ara wíwú Decomposition: Kí ara ó wú. Swelling of the skin or any part of the body. Ìwúra Decomposition: Ara wíwú èyí tí ìsàn-omi púpọ̀ nínú àwọn iṣan ara ṣokùnfà rẹ̀.
Ectopic pregnancy
English (en) Ectopic pregnancy A pregnancy that develops outside the uterus, usually in the fallopian tube. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Embryo, Womb (uterus) Yorùbá (yo) Oyún ìta ilé ọmọ Decomposition: Oyún tó ń dàgbà nínú ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà tó wà níta ilé ọmọ.
Dyspnoea
English (en) Dyspnoea Difficulty or shortness of breath. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Apnoea Yorùbá (yo) Àìlèmí Decomposition: Kí èèyàn má lè mí dáadáa. Ìṣòro àìlèmí dáadáa Decomposition: Ìṣòro tí ó ń mú kí ènìyàn má le è mí dáadáa.
Dysmenorrhoea
English (en) Dysmenorrhoea Painful menstrual periods. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Premenstrual syndrome Yorùbá (yo) Nǹkan oṣù onírora Decomposition: Nǹkan oṣù obìnrin tí ó ń mú ìrora dání. Ìrora ọ̀mìsìmọ̀jọ̀ Decomposition: Ìrora tí obìnrin máa ń rí bí ó bá ń ṣe eélà.
Dose
English (en) Dose The amount of medicine taken at one time. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Flumazenil Yorùbá (yo) Ìwọ̀n oògùn Decomposition:
Doppler scan
English (en) Doppler scan A type of ultrasound used to measure blood flow in blood vessels. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Scan Yorùbá (yo) Ìṣàyẹ̀wò ìṣàn ẹ̀jẹ̀ Decomposition: Fífi ẹ̀rọ ṣe ayẹwo ìṣàn ẹ̀jẹ̀.
