English (en) Kinematics Study of motion without considering forces. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Kinematic Pair Yorùbá (yo) Ìṣípòpadà ohun èlò Decomposition: Ìwáàdí ìṣípò kúrò ohun èlò láti ibìkan lọ sí ibòmìíràn.
Category: Yorùbá
Joule
English (en) Joule A unit of energy in the International System of Units (SI). Other languages: Hausa, Igbo Related terms Kinetic Energy Yorùbá (yo) Ìpín agbára jóòlù Decomposition: Ìpín agbára ti a fi sọrí jóòlù.
Jack
English (en) Jack A device used to lift heavy loads. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Load Yorùbá (yo) Ajẹ́rùsókè Decomposition: Ohun-èlò tí a fi ń já ẹrù tàbí nǹkan tó wúwo sókè. A tool used to lift heavy load or things.
Joint
English (en) Joint A connection between two mechanical components. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Friction Yorùbá (yo) Àsopọ̀ Decomposition: Connection between two components. Oríkèé Decomposition: Oríkèéríkèé (ojú ibi tí ohun méjì ti fẹnubọra). A point where two components connect.
Jet Engine
English (en) Jet Engine Engine that propels an aircraft by expelling jet streams of gases. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Engine Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ agbọ́kọ̀-òfuuufú-fò Decomposition: Ẹ̀rọ alepo rọ̀bì tàbí afẹ́fẹ́ àmúṣagbára tí ó ń mú kí ọkọ̀ inú òfuurufú ó fò lókè. An engine that powers aircraft by turning fuel into...
Jig
English (en) Jig A tool used to guide the movement of tools or workpieces. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Gauge Yorùbá (yo) Atọ́nà ohun èlò Decomposition: Tool that guides the movement of tools
Impeller
English (en) Impeller A rotating component used to move fluids in pumps and turbines. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Fan Yorùbá (yo) Afátẹ́gún-inú-ẹ̀rọ Decomposition: Ẹ̀rọ afátẹ́gún tó wà nínú ẹ̀rọ ìfami, ọkọ̀ ojú omi àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. A rotating part (a fan) inside pumps, boats, etc.
Instrumentation
English (en) Instrumentation Tools and devices used to measure and control physical quantities. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Flywheel Yorùbá (yo) Ohun-èlò ìdiwọ̀n Decomposition: Àwọn ohun-èlò tí à ń lò fi ṣe òdiwọn, òǹkà-iye tàbí àkóso iye nǹkan. Tools & devices used to measure or control variables.
Isothermal Process
English (en) Isothermal Process A process occurring at a constant temperature. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Temperature Yorùbá (yo) Àìyípada ìwọ̀n ìgbónágbóoru Decomposition: Wíwà ìwọ̀n ìgbónágbóoru bákan náà fún ìgbà pípẹ́ láì yí padà. Temperature (thermal) remaining the same or constant (iso) throughout.
Internal Combustion Engine
English (en) Internal Combustion Engine Engine where combustion occurs inside the engine. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Combustion chamber Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ ìjépo tinú-ẹ̀rọ Decomposition: Ẹ̀rọ tí ó ń pèsè agbára nípasẹ̀ jíjó epo rọ̀bì àti afẹ́fẹ́ papọ̀ nínú ẹ̀rọ tìkalárarẹ̀. A type of engine that generates power by burning fuel inside the...