English (en) Thrust Force propelling an aircraft or rocket. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Pressure Yorùbá (yo) Ìbìsíwájú Decomposition: Agbára tó ń ti nǹkan síwájú. The reaction force that pushes or propels an object forward.
Category: Yorùbá
Propulsion
English (en) Propulsion Systems generating thrust to move vehicles (e.g., rockets). Other languages: Hausa, Igbo Related terms Thrust Yorùbá (yo) Ìbì Decomposition: Ètò tàbí ìlànà tí ó ń mú nǹkan ṣípò nípasẹ̀ ìbì (ìtì) sí iwájú, sẹ́yìn, sílẹ̀ tàbí sókè. A method or system used to produce motion by generating thrust that moves an...
Aerodynamics
English (en) Aerodynamics Study of air motion and its interaction with solid objects. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Hydraulics Yorùbá (yo) Ìmọ̀ ẹ̀rọ ìrìn inú afẹ́fẹ́ Decomposition: Ìmọ̀ ẹ̀rọ tó ní ṣe pẹ̀lú u bí àwọn ohun èlò ṣe lè lo afẹ́fẹ́ fún ìrìn yálà lórí ilẹ̀ tàbí lórí òfurufú. Ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ egbé...
Polymer
English (en) Polymer Substance composed of large molecular chains (e.g., plastics). Other languages: Hausa, Igbo Related terms Composite Material Yorùbá (yo) Ìṣújọ-ohun-abáradọ́gba Decomposition: Ṣíṣú jọ papọ̀ àwọn ohun kan náà tí ó bá ara wọn dọ́gba (nǹkan kan náà). Substance formed by combining or aggregation of many small units (monomers) into a large molecular...
Distillation
English (en) Distillation Separating mixtures based on boiling point differences. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Alloy Yorùbá (yo) Ìfamiroyọ Decomposition: Fífa omiro tó wúlò yọ kúrò lára nǹkan. The separation of liquid from a mixture. Word coined from an example like ìpọntí for alcohol distillation and ìfọpo for crude oil refinement. Ìfìgbóná-yà-sọ́tọ̀ Decomposition:...
Heat Exchanger
English (en) Heat Exchanger Device transferring heat between fluids. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Heat Transfer Yorùbá (yo) Agbóoruká Decomposition:
Risk Assessment
English (en) Risk Assessment Identifying and analyzing potential project risks. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Project Management Yorùbá (yo) Ìṣàyẹ̀wò ewu Decomposition: Ṣíṣe àyèwò àwọn ohun tí ó le fa ewu, bí yóò ti pọ̀ tó, àti bí a ti ṣe lè dènà rẹ̀. Àgbéyẹ̀wò ewu Decomposition: Assessment of risks. Ṣíṣe Àgbéyẹ̀wò àwọn...
Project Management
English (en) Project Management Planning and executing projects to achieve goals. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Risk Assessment Yorùbá (yo) Ìṣàkóso iṣẹ́-àkànṣe Decomposition: Ṣíṣe àkóso iṣẹ́-àkànṣe láti yọrí sí rere.
Quality Assurance (QA)
English (en) Quality Assurance (QA) Processes ensuring products meet standards. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Quality Control Yorùbá (yo) Ìlànà iìpójúòṣùnwọ̀n Decomposition: Ìlànà láti ríi pé iṣẹ́ pé ojú òṣùwọ̀n.
Specification
English (en) Specification Exact statement of functional or technical requirements. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Tag (mark or label) Yorùbá (yo) Atọ́ka-ìbámu Decomposition: Ìṣètọ́ka ohun tí ó bá nǹkan mu yálà láti ṣiṣẹ́ tàbí ohun ìtọ̀nà. The description that states what is required for something to be done/work or a prerequisite.
