English (en)
Combustion chamber
An enclosed space in which combustion
takes place, especially in an engine.
Yorùbá (yo)
- Kóló ìsọdiná
Decomposition: Kóló níbi tí a ti ń sọ nǹkan di iná.
[Total: 0 Average: 0]
- Kóló ìjépo
Decomposition: Ìyẹ̀wù (bí i kóló tí à ń fi owó pamọ́ sí) fún ìjópọ̀ epo-rọ̀bì àti afẹ́fẹ́. A chamber of a combustion engine in which the fuel or air mix is burned.
[Total: 0 Average: 0]
- Ilé-agbára alápòótí-ina
Decomposition: Abala tàbí agbọn kan tó dàbí àpótí nínú ẹ̀rọ níbi tí epo ti máa ń jó kí ẹ̀rọ le ṣiṣẹ́. The part of an engine where fuel burns to produce energy. The combustion chamber is like a small room where controlled explosions happen to power the engine.
[Total: 0 Average: 0]