English (en)
Dynamic Balance
Condition where the center of mass is
aligned with the axis of rotation.
Yorùbá (yo)
- Okun Ìgbáradúró
Decomposition: Okun tàbí agbára láti gbé ara dúró láìfì síwá-sẹ́yìn tàbí fì sí ọ̀tún àti òsì, nígbàtí à ń rìn tàbí nígbàtí a wà lójú kan.
[Total: 0 Average: 0]
- Ìdúróṣinṣin ẹ̀rọ-yíyí
Decomposition: Ìlànà tí ó ń mú kí ìgbọ̀nriri tàbí fífì ẹ̀rọ tí ó ń yí dín kù nípasẹ̀ ìdúróṣinṣin. A process that minimises the vibration that occurs when an engine is in rotation.
[Total: 0 Average: 0]