English (en)
Dynamics
Study of forces and motion in
mechanical systems.
Yorùbá (yo)
- Agbára ìṣínípò
Decomposition: Agbára tí ó máa ń mú kí nǹkan ṣí kúrò láti ipò kan sí òmíràn. The force that causes something or an object to move from one point to another.
[Total: 0 Average: 0]
- Agbára Ìrìn
Decomposition: Abala ìmọ̀ ẹ̀rọ tó ní í ṣe pẹ̀lú ẹ̀kọ́ lórí i bí nǹkan tàbí àwọn ohun-èlò ṣe ń rìn àti agbára tó ń ṣe àtìlẹ́yìn àti òdiwọ̀n ìrìn náà. Dynamics is a branch of classical mechanics, and it’s all about motion and the forces that produce it.
[Total: 0 Average: 0]