English (en)
Entropy
Measure of disorder or randomness
in a system.
Yorùbá (yo)
- Òdiwọ̀n àìlétò
Decomposition: Òdiwọ̀n àìní ètò (disorder) tàbí ọ̀kan-ò-jọ̀kan (randomness) nínú ẹ̀rọ, iṣẹ́ tàbí 'ìwà' nǹkan (the state of being) of something.
[Total: 0 Average: 0]
- Ìwọ̀n Ìdàrúdàpọ̀
Decomposition: Òdiwọ̀n ìdàrú àti ìdàpọ̀ nínú ètò kan tàbí òmíràn. The disorder in a system.
[Total: 0 Average: 0]