English (en)
Hot key
A single key or combination of keys
on the keyboard of a computer that
carries out a series of commands.
Yorùbá (yo)
- Àtẹ̀ṣẹ àbùjá
Decomposition: Àtẹ̀papọ̀ àwọn àtẹ̀ṣẹ orí pátákó ìtẹ-ọ̀rọ̀ tí ó máa mú kí ìpàṣẹ ó yára - a combination of keys or single key for quick performance in tasks.
[Total: 0 Average: 0]
- Àtẹ̀ṣẹ amúṣẹ́yá
Decomposition: A key that improves efficiency.
[Total: 0 Average: 0]