Process Control

English (en) Process Control Monitoring or adjusting processes to maintain desired outputs. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Quality Control   Yorùbá (yo) Ìṣèdarí ìgbésẹ̀ Decomposition: Ṣíṣe ìdarí tàbí dídarí ìgbésẹ̀ tí nǹkan máa tọ́ gẹ́gẹ́ bí a bá ti ṣe fẹ́. The practice of monitoring and regulating a process so that it produces the...

Corrosion

English (en) Corrosion Gradual degradation of materials via chemical reactions. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Strain   Yorùbá (yo) Ìyìnrìn Decomposition: Kí nǹkan ó yìnrìn tàbí díbàjẹ́ látàrí ìfaragbá ipa àwùjọ/àyíká ọlọ́jọ́pípẹ́. A material wearing off over time.  Ìjẹrà wẹ́rẹ́wẹ́rẹ́ Decomposition: Kí nǹkan máa bàjẹ́ tàbí jẹrà díẹ̀díẹ̀ nítorí ipa àyíká àti àwọn ohun...

Composite Material

English (en) Composite Material Material made from two or more distinct constituents. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Alloy   Yorùbá (yo) Àdàlú Decomposition: Àwọn ohun èlò tí a dàpọ̀ mọ́ra wọn láti gbé ohun èlò kan tó dára jáde. Material made by combining two or more different materials to create something stronger or better...

Thrust

English (en) Thrust Force propelling an aircraft or rocket. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Pressure   Yorùbá (yo) Ìbìsíwájú Decomposition: Agbára tó ń ti nǹkan síwájú. The reaction force that pushes or propels an object forward.  

Propulsion

English (en) Propulsion Systems generating thrust to move vehicles (e.g., rockets). Other languages: Hausa, Igbo Related terms Thrust   Yorùbá (yo) Ìbì Decomposition: Ètò tàbí ìlànà tí ó ń mú nǹkan ṣípò nípasẹ̀ ìbì (ìtì) sí iwájú, sẹ́yìn, sílẹ̀ tàbí sókè. A method or system used to produce motion by generating thrust that moves an...

Aerodynamics

English (en) Aerodynamics Study of air motion and its interaction with solid objects. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Hydraulics   Yorùbá (yo) Ìmọ̀ ẹ̀rọ ìrìn inú afẹ́fẹ́ Decomposition: Ìmọ̀ ẹ̀rọ tó ní ṣe pẹ̀lú u bí àwọn ohun èlò ṣe lè lo afẹ́fẹ́ fún ìrìn yálà lórí ilẹ̀ tàbí lórí òfurufú. Ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ egbé...

Polymer

English (en) Polymer Substance composed of large molecular chains (e.g., plastics). Other languages: Hausa, Igbo Related terms Composite Material   Yorùbá (yo) Ìṣújọ-ohun-abáradọ́gba Decomposition: Ṣíṣú jọ papọ̀ àwọn ohun kan náà tí ó bá ara wọn dọ́gba (nǹkan kan náà). Substance formed by combining or aggregation of many small units (monomers) into a large molecular...

Distillation

English (en) Distillation Separating mixtures based on boiling point differences. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Alloy   Yorùbá (yo) Ìfamiroyọ Decomposition: Fífa omiro tó wúlò yọ kúrò lára nǹkan. The separation of liquid from a mixture. Word coined from an example like ìpọntí for alcohol distillation and ìfọpo for crude oil refinement. Ìfìgbóná-yà-sọ́tọ̀ Decomposition:...

Heat Exchanger

English (en) Heat Exchanger Device transferring heat between fluids. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Heat Transfer   Yorùbá (yo) Agbóoruká Decomposition:   

Risk Assessment

English (en) Risk Assessment Identifying and analyzing potential project risks. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Project Management   Yorùbá (yo) Ìṣàyẹ̀wò ewu Decomposition: Ṣíṣe àyèwò àwọn ohun tí ó le fa ewu, bí yóò ti pọ̀ tó, àti bí a ti ṣe lè dènà rẹ̀. Àgbéyẹ̀wò ewu Decomposition: Assessment of risks. Ṣíṣe Àgbéyẹ̀wò àwọn...

Scroll to top