English (en) Flywheel A rotating wheel used to store rotational energy. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Engine Yorùbá (yo) Àwo-ayíbírí-ẹsẹ̀-ọkọ̀ Decomposition: Àwo ayíbírí tí ó wà ní ẹsẹ̀ ọkọ̀ tí ó ń mú kí ọkọ̀ ó fà síwásẹ́yìn. The spinning disc (wheels) that propels a vehicle.
Tag: Yoruba
Fluid Dynamics
English (en) Fluid Dynamics Study of fluids in motion and their interactions. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Dynamics Yorùbá (yo) Ìlọbọ̀ omi Decomposition: Lílọ àti bíbọ̀ omi nínú ẹ̀rọ. The movement or flow of fluid in a system.
Fan
English (en) Fan A device used to move air or gases. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Coolant Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ afátẹ́gùn Decomposition: Ẹ̀rọ a-fẹ́-atẹ́gùn.
Fuel Injector
English (en) Fuel Injector Device that introduces fuel into the combustion chamber. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Combustion chamber Yorùbá (yo) Afeposẹ́rọ Decomposition: Ohun tó ń fa epo sínú kóló ìsodina inú ẹ̀rọ - the object that carries fuel into the combustion chamber in the engine. Afeposẹ́rọ Decomposition: Ohun tó ń ta epo...
Friction
English (en) Friction Resistance to motion between two surfaces in contact. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Deformation Yorùbá (yo) Ìgbora Decomposition: Kí ohun méjì ó ra ara wọn pọ̀ tàbí gbo ara papọ̀. Resistance to the motion between two objects sliding or in contact.
Entropy
English (en) Entropy Measure of disorder or randomness in a system. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Inertia Yorùbá (yo) Òdiwọ̀n àìlétò Decomposition: Òdiwọ̀n àìní ètò (disorder) tàbí ọ̀kan-ò-jọ̀kan (randomness) nínú ẹ̀rọ, iṣẹ́ tàbí 'ìwà' nǹkan (the state of being) of something. Ìwọ̀n Ìdàrúdàpọ̀ Decomposition: Òdiwọ̀n ìdàrú àti ìdàpọ̀ nínú ètò kan tàbí òmíràn....
Elasticity
English (en) Elasticity Ability of a material to return to its original shape after deformation. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Deformation, Efficiency Yorùbá (yo) Agbára ìpadàbọ̀sípò Decomposition: Agbára láti padà sí ipò. Agbára ìbọ̀ọ́pò Decomposition:
Exhaust System
English (en) Exhaust System Components that channel exhaust gases away from the engine. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Heat Exchanger Yorùbá (yo) Ètò ìgbèéfín jáde Decomposition: Ètò tí ó ń gbá èéfín tí ó ń ti ara epo rọ̀bì inú ẹ̀rọ jọ tí ó sì ń gbá a jáde síta - the...
Engine
English (en) Engine A machine that converts fuel into mechanical energy. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Instrumentation Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ Decomposition:
Efficiency
English (en) Efficiency Ratio of useful work output to total energy input. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Dynamic Balance Yorùbá (yo) Ìjẹ́ṣẹ́pé Decomposition: Jíjẹ́ iṣẹ́ tí ó yẹ kí nǹkan tàbí ẹ̀rọ ó ṣe pé dé ojú àmì (mùṣèmúṣèe rẹ̀ já múṣémúṣé)- the state of having full capability or being productive.