Dynamic Balance

English (en) Dynamic Balance Condition where the center of mass is aligned with the axis of rotation. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Bearing     Yorùbá (yo) Okun Ìgbáradúró Decomposition: Okun tàbí agbára láti gbé ara dúró láìfì síwá-sẹ́yìn tàbí fì sí ọ̀tún àti òsì, nígbàtí à ń rìn tàbí nígbàtí a wà lójú kan....

Drilling Machine

English (en) Drilling Machine Equipment used for drilling holes in materials. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Accelerator, Brake     Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ ìluhò Decomposition: Ẹ̀rọ tí a fi ń lu ihò tàbí dá ihò lu sí nǹkan.  

Design Engineering

English (en) Design Engineering Discipline focused on designing and optimizing mechanical systems. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Aerospace Engineering     Yorùbá (yo) Ìmọ̀-ẹ̀rọ aṣẹ̀dá ohun-èlò Decomposition: The process of coming up with ideas and creating plans to build useful things like machines, products, tools, or systems.  Ìmọ̀-èrò-ìṣẹ̀dá-nǹkan Decomposition: Ìmọ̀ nípa èrò àti ọgbọ́n àtinúdá...

Deformation

English (en) Deformation Change in shape or size of a material under applied forces. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Elasticity     Yorùbá (yo) Àbùkù  Decomposition: Kí nǹkan ò yàtọ̀ sí bí ó ti ṣe wà tẹ́lẹ̀ látàrí àléébù tàbí ìbùkù ìwọ̀n yálà ìtóbi. Change as a result of a particular defect.  

Dynamics

English (en) Dynamics Study of forces and motion in mechanical systems. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Accelerator     Yorùbá (yo) Agbára ìṣínípò Decomposition: Agbára tí ó máa ń mú kí nǹkan ṣí kúrò láti ipò kan sí òmíràn. The force that causes something or an object to move from one point to another....

Crankshaft

English (en) Crankshaft A shaft that converts reciprocating motion to rotational motion. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Camshaft     Yorùbá (yo) Ọ̀pá-ayíbírí-wọ́rọ́kọ́ Decomposition: Ọ̀pá ayíbírí tí ó tẹ̀ wọ̀rọ̀kọ̀-wọ́rọ́kọ́. A shaft (rod) that is cranked (bent or angled out).  

Coolant

English (en) Coolant A fluid used to remove heat from an engine or machine. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Fan     Yorùbá (yo) Omi amẹ́rọtutù Decomposition: Omi tó ń mú ẹ̀rọ tutù.  

Centrifugal Force

English (en) Compression Ratio Force that acts outward on a body moving in a circular path. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Flywheel     Yorùbá (yo) Ìfìsẹ́gbẹ̀ẹ́ ń'nú òbìrìkítí Decomposition: Fífì sí ẹ̀gbẹ́ ohun tí ó wà nínú òbìrìkítí. Tilting to the side when something is rotating. Agbára ìfìsẹ́gbẹ̀ẹ́ olóbìrípo Decomposition: Agbára àìrí tó ń fi...

Compression Ratio

English (en) Compression Ratio Ratio of the maximum to minimum volume in a combustion chamber. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Combustion chamber     Yorùbá (yo) Ìwọ̀n ìjépo Decomposition: Ìwọ̀n iye epo-rọ̀bì àti afẹ́fẹ́ tí ó jó nínú kóló ìjépo. The degree to which the air-fuel mixture is compressed before ignition.  

Combustion chamber

English (en) Combustion chamber An enclosed space in which combustion takes place, especially in an engine. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Carburator     Yorùbá (yo) Kóló ìsọdiná Decomposition: Kóló níbi tí a ti ń sọ nǹkan di iná. Kóló ìjépo Decomposition: Ìyẹ̀wù (bí i kóló tí à ń fi owó pamọ́ sí) fún ìjópọ̀...

Scroll to top