Camshaft

English (en) Camshaft A shaft with cams that controls the timing of valve openings in an engine. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Crankshaft     Yorùbá (yo) Ọ̀pá-ayíbírí-abara-bí-ẹyin Decomposition: Ọ̀pá ayíbírí tí ó ní àwọn wúnrẹ̀n tí ó fara jọ ẹyin fún gbígbé epo àti afẹ́fẹ́ wọnú ẹ̀rọ. A shaft (rod) with cam (oval...

Carburator

English (en) Carburator A carburetor is a device used in gasoline internal combustion engines to mix air and fuel before they enter the engine. It's a mechanical system that regulates the air-fuel ratio, ensuring proper engine operation. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Heat Exchanger     Yorùbá (yo) Apepomáfẹ́fẹ́múná Decomposition: Ẹ̀rọ tí ó máa...

Gravitation

English (en) Gravitation Force of attraction between two masses. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Friction     Yorùbá (yo) Òòfà Decomposition: Agbára tí ó ń fa nǹkan.  

Brake

English (en) Brake A mechanism used to slow down or stop a vehicle. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Accelerator     Yorùbá (yo) Ìjánu Decomposition: Ohun tí a fi ń dá nǹkan dúró. A yá a lò láti ara okùn tí a ń fi sí ẹṣin lẹ́nu. The term was borrowed for use in vehicles...

Boiler

English (en) Boiler A device for generating steam or hot water. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Adiabatic Process     Yorùbá (yo) Amómigbóná Decomposition: Ohun èlò tó ń mú omi gbóná.  

Bolted Joint

English (en) Bolted Joint A connection using bolts to fasten components. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Key     Yorùbá (yo) Òǹdè olóòka Decomposition: Ohun tí a fi ń de nǹkan papọ̀ tí ó rí róbótó bí òòka. A fastener that is round like a ring. Ìsopọ̀-ẹ̀rọ olóǹdè Decomposition: A mechanical connection that uses bolts...

Bending Moment

English (en) Bending Moment The internal moment that induces bending of a beam. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Alloy     Yorùbá (yo) Amúrintẹ̀ Decomposition: Ohun tó ń mú kí irin tẹ̀. The force that causes a beam or shaft to bend. Agbára amóhunèlòtẹ̀ Decomposition: Amú-ohun-èlò-tẹ̀. Agbára tó ń mú kí òpó gbọọrọ agbẹrù-sórí...

Bearing

English (en) Bearing In engineering, a bearing is a machine element that constrains relative motion and reduces friction between moving parts, typically to facilitate smooth rotation or linear movement. Bearings are crucial in supporting loads (radial, axial, or combined) while allowing controlled motion with minimal energy loss. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Pulley  ...

Ammeter

English (en) Ammeter Instrument for measuring electric current. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Instrumentation     Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ ìwọ̀n mànàmáná Decomposition: Ohun-èlò tí a fi ń ṣe òǹdiwọ̀n ipa tàbí agbára iná mànàmáná. An instrument used in measuring the current of electricity in a circuit. Ẹ̀rọ ìfidíwọ̀n mànàmáná Decomposition: Ohun èlò tí a...

Alloy

English (en) Alloy An alloy is a mixture of two or more metals (or a metal and another element) combined to make a material that is stronger or better in some way than the individual metals on their own. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Zinc Plating     Yorùbá (yo) Àdàlù-irin Decomposition: Irin tí ó...

Scroll to top