English (en) IoT (Internet of Things) Network of interconnected devices with sensors/software. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Connection, Internet Yorùbá (yo) Ìsopapọ̀ ohun orí-ayélujára Decomposition: Ìsopapọ̀ àwọn ohun-èlò àrígbámú tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ papọ̀ lórí ẹ̀rọ-ayélujára. Network of physical ejects that are connected the internet so they can collect, send and receive data....
Category: Engineering
API (Application Programming Interface)
English (en) API (Application Programming Interface) Rules enabling software components to communicate. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Interface (software) Yorùbá (yo) Oríta-ìbáṣepọ̀ Ohun-èlò Decomposition: Ojú ibi tí àwọn ohun-èlò (méjì tàbí jù bẹẹ̀ lọ) ti ń bá ara wọn ṣiṣẹ́ papọ̀. A set of rules/point where two software systems meet, interact and share information...
Semiconductor
English (en) Semiconductor Material with conductivity between conductor and insulator. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Current Yorùbá (yo) Agbanásáradíẹ̀ Decomposition: Ohun tí ó lágbára yálà láti gba iná mànàmáná tàbí láti má gbaná sí ara. A material used in electrical circuits and components that partially conducts electricity.
PCB (Printed Circuit Board)
English (en) PCB (Printed Circuit Board) A board connecting electronic components via conductive pathways. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Circuit Yorùbá (yo) Pátákó atòòyìká Decomposition: Ike bíi pátákó pẹrẹsẹ tí àwọn ìlẹ̀-agbóòyìká wà. A flat board that holds and connects chips.
Microcontroller
English (en) Microcontroller A compact IC for controlling specific operations. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Control Yorùbá (yo) Ẹ̀rọ-aṣàkóso-kíún Decomposition: Ẹ̀rọ ayárabíàṣà ṣíńṣín jọjọ fún ìṣàkóso àwọn iṣẹ́ kan pàtó. A tiny computer which runs a specific program and control one machine.
Current
English (en) Current Rate of flow of electric charge. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Power Yorùbá (yo) Agbára iná Decomposition: The power or rate of electric charge Ìṣàn-agbára-iná Decomposition: Òṣùwọ̀n ìṣàn agbára iná-mànàmáná. The rate of electric power flow.
Circuit
English (en) Circuit A closed path allowing electric current to flow. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Current Yorùbá (yo) Àtọ̀yíká Decomposition: Àtọ̀yíká òyì iná mànàmáná. Going round of electric current.
Tolerance
English (en) Tolerance Permissible limit of variation in a physical dimension. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Power Yorùbá (yo) Ìyàtọ̀ ìwọ̀n ìbámu Decomposition: Ìyàtọ̀ ìwọ̀n (ìtóbi tàbí kíkéré) tí a fàyè gbà fún ìbámu ohun. The acceptable amount of variation in a measurement or dimension.
Fatigue
English (en) Fatigue Material weakening due to cyclic loading. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Overhaul Yorùbá (yo) Ìdẹra Decomposition: Kí ohun ó dẹ ara látàrí ẹrù gbígbé lọ́pọ̀ ìgbà. Weakness of a material over time when it is exposed to repeated or fluctuating loads.
Fluid Mechanics
English (en) Fluid Mechanics The study of fluids (liquids/gases) and forces acting on them. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Fluid Dynamics Yorùbá (yo) Ìmọ̀ ìhùwàsí omi Decomposition: Ìmọ̀ tí ó dá lórí ìwádìí sí ìhùwàsí omi yálà ní ojúkan tàbí bí ó bá ń ṣàn. Knowledge of the study of how fluids behave when...
