BIM (Building Information Modeling)

English (en) BIM (Building Information Modeling) A 3D model-based process for building design and management. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Foundation   Yorùbá (yo) Ìfàwòránṣàpẹrẹ Ètò Ilé-kíkọ́ (IEI) Decomposition: Fífi àwòrán ṣe àpẹẹrẹ ètò àti àkóso àwọn ohun èlò fún ilé kíkọ́ láti wo bí yóò ṣe rí lẹ́yìn tí wọ́n bá kọ ọ́ tán....

Surveying

English (en) Surveying Measuring and mapping land and terrain features. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Foundation   Yorùbá (yo) Wíwọnlẹ̀ Decomposition: Wíwọn ilẹ̀, àti ṣíṣe ìfisísọ̀rí àbùdá àti ìrísí ojú ilẹ̀. Measuring and categorizing land based on its features.  

Geotechnical Engineering

English (en) Geotechnical Engineering The study of soil and rock behaviour for construction. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Surveying   Yorùbá (yo) Ìmọ̀ ìdára-ilẹ̀-fún-kíkọ́ (ohun) lé Decomposition: Ìmọ̀ òfíntótó ìdára tó ojú ilẹ̀ ibi tí a fẹ́ kọ́ nǹkan sí. Study that shows whether the soil, rock, and groundwater conditions at a site are...

Load-Bearing Wall

English (en) Load-Bearing Wall A wall supporting weight from elements above it. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Column   Yorùbá (yo) Ògiri-agbẹ́rù Decomposition:   

Reinforcement

English (en) Reinforcement Steel bars (rebar) used to strengthen concrete under tension. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Concrete   Yorùbá (yo) Afún-kannkéré-lókun Decomposition: Ohun èlò tó ń fún òkúta kannkéré lókun láti lè ru ẹrù tàbí gbé ohun tó wúwo.  

Concrete

English (en) Concrete A composite material of cement, aggregate, and water. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Foundation   Yorùbá (yo) Òkúta Kannkéré Decomposition: Concrete: a very strong artificial stone created by mixing cement, sand, gravel, and water. When this mixture hardens, it becomes solid and can carry heavy loads.  

Foundation

English (en) Foundation The base that transfers structural loads to the ground. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Load   Yorùbá (yo) Ìpìlẹ̀ Decomposition: The base or foundation.  

Column

English (en) Column A vertical element transmitting compressive forces to the foundation. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Vertical scroll bar   Yorùbá (yo) Òpó Decomposition: Òpó rìbìtì tí ó ń gba ipa ẹrù sílẹ̀. A pillar that transmits force beneath a structure.  

Beam

English (en) Beam A horizontal structural element that resists loads applied laterally. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Load   Yorùbá (yo) Agbẹ́rùró Decomposition: Ohun tí ó ń gbé ẹrù dání. A structural member designed to carry and transfer loads to supports.  

Zone of Influence

English (en) Zone of Influence The area affected by a force or load in a mechanical system. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Mechanical Advantage   Yorùbá (yo) Ibi ìfaragbá Decomposition: Ibi tí ó fi ara gbá. Area affected by a force. Ibi ipa Decomposition: Ọ̀gangan ibi tí ipa ẹrù tàbí ohunkóhun mú àyípadà bá. An...

Scroll to top