English (en) Circulatory system The system that circulates blood and lymph through the body. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Coronary artery Yorùbá (yo) Ètò Ìṣàn-ẹ̀jẹ̀ Decomposition: Ètò bí ẹ̀jẹ̀ ṣe ń ṣàn káàkiri nínú àgọ́ ara. The system of the movement of blood around the body.
Category: Medical
Chronic
English (en) Chronic A condition that is long-lasting or recurrent. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Acute Yorùbá (yo) Ọlọ́jọ́-pípẹ́ Decomposition: Àìsàn tí ó ti pẹ́ nínú àgọ́ ara (àìsàn tí ó ti gbógàn síni lára). Bí àpẹẹrẹ: Ọmọbìnrin náà ní ẹ̀fọ́rí ọlọ́jọ́-pípẹ́ - the girl has a chronic headache.
Cholesterol
English (en) Cholesterol A type of fat found in the blood, essential in small amounts but harmful in excess. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Triglyceride Yorùbá (yo) Ọ̀rá inú ẹ̀jẹ̀ Decomposition: A fat-like substance found in the blood and body.
Chemotherapy
English (en) Chemotherapy The use of drugs to treat diseases such as cancer. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Cancer Yorùbá (yo) Ìfòògùn-pa-jẹjẹrẹ Decomposition: Lílo oògùn àkànṣe láti pa tàbí tọ́jú àrùn jẹjẹrẹ. Medical treatment that uses strong drugs to kill fast-growing cells in the body, especially cancer cells. Ìfòògùndẹ́kun Decomposition: Fífi (using) òògùn...
Cervical
English (en) Cervical Relating to the neck or the cervix. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Cervical cord, Vagina Yorùbá (yo) Ajẹmọ́ àbáwọlé ilé-ọmọ Decomposition: Ajẹmọ́ eegun ọrùn Decomposition: Cervical usually refers to the upper part of the spine in the neck region (the 7 bones in your neck called the cervical vertebrae).
Cerebral
English (en) Cerebral Relating to the brain. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Cortex Yorùbá (yo) Ajẹmọ́ ọpọlọ. Decomposition:
Cell
English (en) Cell The smallest structural and functional unit of an organism. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Necrosis Yorùbá (yo) Pádi Decomposition: Pádi tí ó jẹ́ ẹ̀yà-ara tó kéré jù nínú àgọ́ ara. A bunch of enclosed small bit of life in human. Hóró Decomposition: Smallest unit of an organism.
Cataract
English (en) Cataract A condition in which the lens of the eye becomes progressively opaque. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Xerophthalmia Yorùbá (yo) Àtafọ́ ojú Decomposition: Títafọ́ àwo ẹyin ojú. Kùrukùru ojú Decomposition: Clouding of the eye Ìṣókùnkùn ojú Decomposition: Àìsàn ojú tí ó ń mú kí àwo ojú ó ṣókùnkùn.
Cardiology
English (en) Cardiology The branch of medicine dealing with disorders of the heart. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Aorta Yorùbá (yo) Ẹ̀ka ìṣẹ́gun ìlera ọkàn Decomposition: Ìmọ̀ ìṣẹ́gun àti ìlera ọkàn. Èka ìṣègùn nípa ìdààmú ọkàn Decomposition:
Carbohydrate
English (en) Carbohydrate A type of nutrient that is the main source of energy for the body. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Nutrison Yorùbá (yo) Oúnjẹ afúnilókun Decomposition: Àwọn oúnjẹ tí ó ní ẹlà-okun. Èròjà afáralókun Decomposition: Ingredient that gives the body strength. Ẹ̀ka ìṣègùn ajẹmọ́kàn- the branch of medicine that deals with...
