Cancer

English (en) Cancer A disease caused by an uncontrolled division of abnormal cells in a part of the body. Other languages: Hausa, Igbo Related terms BRCA   Yorùbá (yo) Àrùn jẹjẹrẹ Decomposition: Tí a tún máa sábà pè ní jẹjẹrẹ.  

Breech position

English (en) Breech position Baby lying bottom first in the womb before birth. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Embryo, Fetus   Yorùbá (yo) Ipò Ìgè Decomposition: Ọmọ tí ó wà ní ipò Ìgè (ẹsẹ̀ ni ó wà nísàlẹ̀ dípò orí) nínú oyún. A child in the position of Ìgè (child born with leg out...

BRCA

English (en) BRCA Breast Cancer genes (BRCA1 and BRCA2) associated with higher risk of several cancers. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Cancer   Yorùbá (yo) Ìràn jẹjẹrẹ ọmú Decomposition: Breast cancer genes - àwọn ìran (genes) jẹjẹrẹ (cancer) ọmú (breast) tí wọ́n ní (that have) ewu onírúurú (various risk) jẹjẹrẹ (cancer) tí ó pọ̀...

Brachial plexus injury

English (en) Brachial plexus injury Damage to nerves in a baby’s neck affecting arm movement. Other languages: Hausa, Igbo Related terms   Yorùbá (yo) Àìlègbọ́wọ́ Decomposition: Ìfarapa (injury) sí àwọn ẹ̀yà aṣèmọ̀lára (to the nerves) ní ọrùn ìkókó (baby's neck) tí ó ń ṣe àkóbá fún (that is affecting) yíyí ọwọ́ (moving hand) Ìpalára ẹ̀sọ...

Body mass index (BMI)

English (en) Body mass index (BMI) A measurement of healthy weight range based on height and weight. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Boyd’s equation   Yorùbá (yo) Atọ́ka Ìtẹ̀wọ̀n Ara Decomposition: Atọ́ka ìyàtọ̀ ìníkìmì àti ìgà ènìyàn. Number showing a person’s weight in relation to their height.  

Blood group

English (en) Blood group Classification of blood based on antigens on red blood cells (A, B, AB, O types). Other languages: Hausa, Igbo Related terms Haemorrhage   Yorùbá (yo) Irúfẹ́ ẹ̀jẹ̀-ara Decomposition: Irúfẹ́ ẹ̀jẹ̀ tí ènìyàn ní lára èyí tí wáyé nítorí àwọn atọ́ka ohun àjèjì inú hóró ẹ̀jẹ̀ pupa. Blood type in a person's...

Bladder training

English (en) Bladder training A way of teaching the bladder to hold more urine and reduce urgency. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Bladder   Yorùbá (yo) Ìpàtọ̀mọ́ra Decomposition: Kíkọ́ ilé-ìtọ̀ láti lè pa ìtọ̀ mọ́ra/gba ìtọ̀ dúró díẹ̀ síi. Teaching the bladder to hold more urine.  

Bladder

English (en) Bladder Organ that stores urine before it is passed out through the urethra. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Bladder training   Yorùbá (yo) Ilé-ìtọ̀ Decomposition: Ẹ̀yà ara tí ó máa ń gba ìtọ̀ dúró. Organ that stores urine.  

Birth asphyxia

English (en) Birth asphyxia Reduced oxygen level around the time of birth, causing breathing issues or low heart rate. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Anoxia   Yorùbá (yo) Àìlèmí lákòókò ìbí Decomposition: Àìrí èémí mí ọmọ ìkòkò nígbà tí ó ń wá sáyé. Baby not getting enough oxygen around the time they were born....

Biopsy

English (en) Biopsy The taking of a small sample of tissue for examination. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Autopsy   Yorùbá (yo) Àyẹ̀wò ẹ̀ya-ara-kékeré-jù-lọ Decomposition: Mímú díẹ̀ lára àwọn ẹ̀ya ara tí ó kéré jù lọ fi ṣe àyẹ̀wò tàbí ìdánwò.To take a tiny sample from the body to investigate it carefully.  

Scroll to top