Polymer

English (en) Polymer Substance composed of large molecular chains (e.g., plastics). Other languages: Hausa, Igbo Related terms Composite Material   Yorùbá (yo) Ìṣújọ-ohun-abáradọ́gba Decomposition: Ṣíṣú jọ papọ̀ àwọn ohun kan náà tí ó bá ara wọn dọ́gba (nǹkan kan náà). Substance formed by combining or aggregation of many small units (monomers) into a large molecular...

Distillation

English (en) Distillation Separating mixtures based on boiling point differences. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Alloy   Yorùbá (yo) Ìfamiroyọ Decomposition: Fífa omiro tó wúlò yọ kúrò lára nǹkan. The separation of liquid from a mixture. Word coined from an example like ìpọntí for alcohol distillation and ìfọpo for crude oil refinement. Ìfìgbóná-yà-sọ́tọ̀ Decomposition:...

Heat Exchanger

English (en) Heat Exchanger Device transferring heat between fluids. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Heat Transfer   Yorùbá (yo) Agbóoruká Decomposition:   

Risk Assessment

English (en) Risk Assessment Identifying and analyzing potential project risks. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Project Management   Yorùbá (yo) Ìṣàyẹ̀wò ewu Decomposition: Ṣíṣe àyèwò àwọn ohun tí ó le fa ewu, bí yóò ti pọ̀ tó, àti bí a ti ṣe lè dènà rẹ̀. Àgbéyẹ̀wò ewu Decomposition: Assessment of risks. Ṣíṣe Àgbéyẹ̀wò àwọn...

Project Management

English (en) Project Management Planning and executing projects to achieve goals. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Risk Assessment   Yorùbá (yo) Ìṣàkóso iṣẹ́-àkànṣe Decomposition: Ṣíṣe àkóso iṣẹ́-àkànṣe láti yọrí sí rere.  

Quality Assurance (QA)

English (en) Quality Assurance (QA) Processes ensuring products meet standards. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Quality Control   Yorùbá (yo) Ìlànà iìpójúòṣùnwọ̀n Decomposition: Ìlànà láti ríi pé iṣẹ́ pé ojú òṣùwọ̀n.  

Specification

English (en) Specification Exact statement of functional or technical requirements. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Tag (mark or label)   Yorùbá (yo) Atọ́ka-ìbámu Decomposition: Ìṣètọ́ka ohun tí ó bá nǹkan mu yálà láti ṣiṣẹ́ tàbí ohun ìtọ̀nà. The description that states what is required for something to be done/work or a prerequisite.  

Calibration

English (en) Calibration Configuring instruments for accurate measurement. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Quality Control   Yorùbá (yo) Ìyòǹdiwọ̀nṣegééré Decomposition: Yíyí ohun èlò òdiwọ̀n láti ṣiṣẹ́ géérégé. Adjusting, and setting a device or system so its measurements are accurate.  

Optimization

English (en) Optimization Process of maximizing performance or minimizing waste. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Quality Control   Yorùbá (yo) Ìmúṣisẹ́dáradára Decomposition: Ìlànà mímú nǹkan ṣiṣẹ́ ju bí ó ti ṣe wà lọ. The process of improving something so it works as well as possible.  

Prototype

English (en) Prototype A preliminary model for testing and evaluation. Other languages: Hausa, Igbo Related terms Alpha-test   Yorùbá (yo) Àwòṣe-àkọ́kọ́ Decomposition: Àwòṣe tí ó jẹ́ àkọ́kọ́ irú ẹ̀. The first or earliest model of something.  

Scroll to top